Get Even More Visitors To Your Blog, Upgrade To A Business Listing >>

Blog Directory  >  Blogging Blogs  >  Online Yoruba Teacher blogging Blog  > 

2022-12-14 03:25
Bi a ba n soro nipa awon orisa nile Yoruba, tabi ka so wi pe ti a ba so nipa awon ibo (awon babanla awon Yoruba), won po sua bi omi ti ko see ka. Amo a o lo anfaani yii lati fi menu ba die l… Read More
Project Wolf Hunting 2022
2022-11-25 21:38
During transport from the Philippines to South Korea, a group of dangerous criminals unites to stage a coordinated escape attempt. As the jailbreak escalates into a bloody, all-out riot, the… Read More
Moremi Ajasoro Lati Owo Debo Awe
2022-11-17 15:19
Moremi Ajasoro lati owo Debo AweMoremi Ati Awon Obi Re Moremi je omo bibi inu Oluronbi ati Adelaja, awon iwin-igbo lo gbe baba Moremi lo bee ni iya re ti n se Oluronbi je akoni obinrin to ba… Read More
2022-11-04 00:22
Taamu: 1stOse: 4thKilaasi: Sekondiri kekere keji (j. s. s. 2)Deeti: Put Your Own DateAkori: Rara SisunAfojusun: Leyin eko yii, awon akekoo yoo ti ni ekunrere imo nipa rara sisun.Ifaara: Oluk… Read More
2022-10-17 23:12
Ni aye atijo, awon Yoruba kii foju kere ajosepo idi niyi ti won fi ma n pa owe pe “ki arin ki a po, yiye nii yeni”, “Ajeji owo kan ko gbe eru dori”Yoruba ni awon ona… Read More
Aso Wiwo Nile Yoruba
2022-10-02 11:19
Ese ifa kan to fi iwulo aso wiwo han, lo bayii pe:"Bi a ti rin ni a a koniBi a ba rin irin obunTi a woso ise woluOjukoju ni won mu wo niIgbakigba ni won i mu bomi i fun ni muO difa fun Alejo… Read More
2022-09-17 15:28
Image from Google SearchOhun ti o n fa ogun jija: Lara awon ohun ti o maa n mu ki ogun jija be sile lawujo Yoruba, laye atijo, ni a ti ri egun agbara awon alagbara, aala ile, ife lati konile… Read More
2022-08-04 19:31
E je ki a lo anfaani yii lati se agbeyewo die lara awon Akanlo Ede Pelu Itumo Won.1. Ayírí: Eni ti ara re ko bale2. Tiraka: Gbiyanju lati se nnkan.3. Bònkél&eacut&hell…Read More
2022-07-20 08:39
 1. Aroko tumo si ________2. Daruko orisii arok ____________(i) ___________ (ii) ___________ (iii) __________ (iv) _____________ (v) ___________3. Ijamba oko ni oju popo je mo aroko ___… Read More
Oriki
2022-07-20 02:53
Oriki je oro ti a maa n lo lati fi bu ewa kun oruko tabi ipo eniyan lawujo Yoruba. O le je oro soki tabi jantirere.Die lara ipin oriki ni oriki abiso, oriki amutorunwa, oriki borokini, oriki… Read More
Aroko (Yoruba Essay Writing)
2022-07-20 02:51
Ki ni Aroko?Ko se e ma ni ni aroko kiko (essay writing), idi abajo si ni pe o maa n fi han bi iriri ati ogbon atinuda akekoo se rinle si. Yato si eyi, aroko kiko tun maa n je ki a mo bi akek… Read More
Orin Nile Yoruba
2022-07-20 02:51
Orin je akojopo gbolohun ede Yoruba ti afi ohun didun gbe jade. O see patewo si. A le lu ilu sii. A si le jo sii nigba miiran. A tun le sope Orin je ona ti a ngba fi ero in eni han pelu ohun… Read More
2022-05-12 09:05
 3000 = eedegbaaji = 2000 x 2 - 1000 (egbaa meji din egberun)4000 = egbaaji = 2000 x 2 ( egbaa meji)5000 = eedegbaata = 2000 x 2 - 1000 (egbaa meta din egberun)6000 = egbaata = 2000 x 3… Read More
2022-04-18 13:58
O se Pataki ki a mo wipe aroko ariyanjiyan gbodo tele akoto ode – oni. Ede tabi Yoruba ajumolo se Pataki ninu kiko aroko yii. Lilo awon ewa – ede bii owe, akanlo ede, afiwe ati b… Read More
Oruko Oye Awon Oba Nile Yoruba
2021-06-14 19:36
E je ki a lo anfaani lati se atunyewo oruko oye awon oba nile Yoruba. Eko yii ro mo asa oye jije nile Yoruba; a maa se ekunrere alaye lori asa oye jije laipe ni ihin yii. Ninu eko naa ni a t… Read More
Orisirisi Oro-Ise 2
2021-06-08 03:32
ORISI ORO-ISE APERRE WON 1.  oro-ise akanmoruko/aigbabo Peran: Won peran 2. oro-ise aigbabo Ji: Tola ji isu/ Tola ji i 3. oro-ise elela Baje: Akekoo ba aga je 4. oro-ise ailela Gba… Read More
2021-06-04 17:42
Ninu asa ti o se Pataki julo ni ede Yoruba ni biba ara eni soro lailo oro enu. Awon Yoruba tile ka omo ti o ba mo oju tun mo ti o gbon ti o si ni aye gidigidi. Yoruba le so igba oro lailo or… Read More
Ami Ohun Ati Apeere
2021-06-03 17:40
Didun ohun se pataki pupo ninu ede Yoruba. Orisi ohun meta ni ede Yoruba ni. Awon ohun naa ni wonyii:(1) Ohun isale(2) Ohun aarin(3) Ohun okeBi a ba n ko ede Yoruba sile, a maa n lo awon ami… Read More
Nitori Owo Lati Owo Akinwumi Isola
2021-06-01 16:18
Nitori Owo lati owo Akinwumi Isola je iwe ere onise to ni iran mokanla (11 scenes). Awon eda itan ni Oyeladun (olu eda itan), Adijatu, Baba Adio, Oladejo, Adio, Adu, Bosipo, Bayo, ati bee lo… Read More
2021-05-28 20:04
Itan ye wa wi pea won oyinbo ati awon ojise olorun lati America lo koko bere akitiyan kiko ede Yoruba sile. Awon yoeuba ko ni imo mo-on-ko-mo-on-ka gbogbo ohun ti won mo, inu opolo won ni wo… Read More

Share the post

Online Yoruba Teacher

×

Subscribe to Online Yoruba Teacher

Get updates delivered right to your inbox!

Thank you for your subscription

×